Kùwéìtì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Kùwéìtì
Remove ads

Orílẹ̀-èdè Kùwéìtì (Lárúbáwá: دولة الكويت, pronounced [dawlat alkuwayt]) je Ile-Emiri Arabu aladani to ni bode mo Saudi Arabia ni guusu ati Irak ni ariwa ati iwoorun. Ijinna to pojulo lati ariwa de guusu je 200 km (120 mi) ati lati ilaoorun de iwoorun je 170 km (120 mi). Iposieniyan re je 2.889 legbegberun ati agbegbe 18,098 km².

Quick Facts Orílẹ́-ẹ̀dẹ̀ Kùwéìtì State of Kuwait دولة الكويت Dawlat al-Kuwayt, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...


Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads