Màláwì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Màláwì
Remove ads

Màláwì (play /məˈlɑːwi/; Chichewa Àdàkọ:IPA-ny), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Màláwì, je orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ kan ni guusuilaorun Afrika to je mi mo tele bi Ilẹ̀ Nyasa. O ni bode mo Zambia ni ariwaiwoorun, Tanzania ni ariwailaorun, ati Mozambique ni ilaorun, guusu ati iwoorun. Orile-ede na je pinpinniya si Tanzania ati Mozambique pelu Omi-adagun Malawi. Malawi tobi to 118,000 km2 (45,560 sq mi) pelu awon alabugbe ti idiye won ju 13,900,000 lo. Oluilu re ni Lilongwe, to tun je ilu totobijulo ni be; ikeji totobijulo ni Blantyre ati iketa ni Mzuzu. Malawi bi oruko re wa lati Maravi, oruko atijo fun awon Nyanja ti won budo si be. Won tun unpe orile-ede yi bi "Ọkàn Alọ́wọ́rọ́ Afrika".[8]

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ MàláwìRepublic of Malawi [Chalo cha Malawi, Dziko la Malaŵi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...




Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads