Maseru

From Wikipedia, the free encyclopedia

Maserumap
Remove ads

Maseru ni oluilu orile-ede Lesotho. Bakanna ibe tun ni ibujoko Ipinleagbegbe Maseru. O budo si eti Odo Mohokare, ni bode mo orile-ede Guusu Afrika, Maseru nikan ni ilu totobi ni Lesotho pelu olugbe to to 227,880 (2006).

Quick facts Country, District ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads