Nat King Cole

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Nat King Cole
Remove ads

Nathaniel Adams Coles (March 17, 1919 February 15, 1965), to gbajumo nibise bi Nat "King" Cole, jeolorin ara Amerika to koko gbajumo bi okan ninu awon atepiano jazz. Botilejepe o yorisirere bi atepiano, 0hun baritonu re ni awon eniyan se mo, to unlo lati korin larin agbo nla ati awon iru orin jazz. Ohun ni eni alawodudu ara Amerika akoko to je agbalejo ere orisirisi lori telifison, beesini o ti gbajumo kakiri agbaye nitori iku aitojo re; o je gbigba bi ikan ninu awon olorin pataki to koja ni orile-ede Amerika.

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads