Májẹ̀mú Titun

From Wikipedia, the free encyclopedia

Májẹ̀mú Titun
Remove ads

Majẹmu titun[note 1] ni ìpín kejì tí Bíbélì mímọ Kristẹni. Ó sọ nípa àwọn ẹ̀kọ́ àti ìgbẹ́ ayé Jesu,o tún sọ nípa ìgbé ayé àwọn Kristẹni.

Thumb
Májẹ̀mú Titun

Májẹ̀mú titun jẹ́ àpapọ̀ àwọn ìwé Kristẹni tí wón ko ní èdè Griki, oríṣi àwọn ènìyàn mimo ni ó ko àwọn ìwé yìí. Majẹmu titun ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjọ jẹ́ àpapọ̀ ìwé metadinlogbon.

  • Àwọn ìwé Ìhìn réré mẹ́rin(Mátíù, Maru, Lúùkù àti Jòhánù).
  • Ìwé ìṣe àwọn Àpọ́sítélì
  • Àwọn ìwé mẹ́tàlá Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù
  • Ìwé sí àwọn Hébérù
  • 7 Àwọn ìwé méje sí àwọn Kristẹni
  • Ìwé ìfihàn.
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads