Ìpínlẹ̀ Niger
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Niger jẹ́ Ìpínlẹ̀ kan ààrin gbùngbùn apá àríwá lórílẹ̀-èdè Nigeria. Ó jẹ́ Ìpínlẹ̀ tó tóbi jù lọ ní Nàìjíríà. Wọ́n pín Ìpínlẹ̀ Niger sí àgbègbè-ìṣèjọba mẹ́ta, ní ìpín A, B, D. Minna ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Niger. Àwọn ìlú ńlá mìíràn tí wọ́n wà ní Niger; Bida, Kontagora and Suleja.[4][5] Wọ́n dá Ìpínlẹ̀ Niger lọ́dún 1976.[4] Ó jẹ́ ìlú àwọn Ààrẹ-àná ológun, ọ̀gágun Ibrahim Babangida àti Abdulsalami Abubakar. Àwọn ènìyàn Nupe, Gbagyi, Kamuku, Kambari, Gungawa, Hun-Saare, Hausa àti Koro ni wọ́n pọ̀jù ní Ìpínlẹ̀ náà.[6]
Remove ads
Orúkọ odò Niger ni wọ́n fi sọrí Ìpínlẹ̀ náà. Ìpínlẹ̀ náà ni odò tí wọ́n fi ń pèsè iná-ọba, Kainji Dam àti Shiroro Dam, bẹ́ẹ̀ náà, ibẹ̀ ni Zungeru Dam wà. Ibẹ̀ ni Jebba Dam tí ní ìpín ní Ìpínlẹ̀ Niger àti Ìpínlẹ̀ Kwara. Ibẹ̀ náà ni Gurara Falls, tí wọn fi orúkọ odò Gurara sọrí wà.[7] Also situated there is Kainji National Park, the largest National Park of Nigeria, which contains Kainji Lake, the Borgu Game Reserve and the Zugurma Game Reserve.[8]
Remove ads
Àwọn èdè wọn
Àwọn wọ̀nyí ni èdè tí wọ́n ń sọ ní Ìpínlẹ̀ ní ìpín ìjọba-ìbílẹ̀ wọn:[9]
Sorko and Zarma are also spoken.[9]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads