Ajagun Ojúomi Nàìjíríà

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ajagun Ojúomi Nàìjíríà
Remove ads

Ile-ise Ajagun Ojúomi Nàìjíríà (tabi Nigerian Navy (NN)) ni apa ajagun ojuomi ile-ise ologun Naijiria. Ajagun Ojúomi Nàìjíríà ni ikan ninu awon ajagun ojuomi to tobijulo ni Afrika. O ni awon omo-ogun to to 7 000 personnel, ti Ile-ise Eso Eti-Odo (Coast Guard) na je ikan ninu re.

Quick facts Nigerian Navy, Ìgbéṣe ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads