Ẹ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ẹ̀bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀ (Àdàkọ:Lang-sv) jẹ́ ẹ̀bùn ọlọ́dọọdún, láti 1901, tí wọ́n máa ń fun àwọn oǹkọ̀wé láti orílẹ̀-èdè yìówù tí wá, gẹ́gẹ́ bí ogun Alfred Nobel ṣe sọ, o se "ninu papa litireso ise pataki lona to daa" (ni ede Sweden: den som inom litteraturen har producerat det utmärktaste i idealisk riktning).[1][2] Akademi Swidin lo n pinnu tani, ti onitoun ba wa, yio gba ebun na ninu odun kan, won si n sekede oruko onitoun ninu osu kewa odun.[3]

![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads