Oluseyi Makinde
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Olusèyí Abiọ́dún Mákindé ni a bí ní ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1967 (25 December 1967). Ó jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú àti ọlọ́rẹ àtinúwá Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà tí ó ń bẹ lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1] ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Wọ́n dìbò yàn-án ní Ọdún 2019 lábé àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) Ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas Metering).[3]
Remove ads
Ibere pepe aye re ati eko
A bi makinde si ile Pa Olatubosun Makinde, ati Abigail Makinde ni adugbo Aigbofa, Oja’ba, ni ilu Ibadan, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ọ̀un ni awon obire bi siketa.[2][3] Makinde bere eko re ni Ile eko-ibere St Paul primary school. O pari eko- Ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ni St Michael Primary School,ni Ye metu. Makinde se eko girama ní Bishop Phillips Academy[4]. Ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ìlú Èkó níbi tó ti gba ìwé-ẹrí bachelor degree nínú ìmò Electrical Engineering.
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads