Pólándì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Pólàndì /ˈpoʊlənd/ (ìrànwọ́·info) (Pólándì: [Polska] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Poland (Rzeczpospolita Polska), je orile-ede ni Aarin Europe [6][7] to ni bode mo Jẹ́mánì si iwoorun; Tsek Olominira ati Slofakia si guusu; Ukraine, Belarus ati Lituéníà si ilaorun; ati Okun Baltiki pelu Kaliningrad Oblast, to wa ni Rosia, ni ariwa. Gbogbo ifesi agbegbe ile Poland je 312,679 square kilometres (120,726 sq mi),[3] to so di orile-ede 69th titobijulo ni aye ati ikesan titobijulo ni Europe. Poland ni iye awon eniyan to ju 38 legbegberun lo,[3] eyi so di orile-ede 34th toleniyanjulo ni aye[8] ati ikan ninu awon toleniyanjulo ni Isokan Europe.
Idasile orile-ede Poland bere pelu Esin Kristi latowo Mieszko I olori ibe, ni odun 966, nigbati orile-ede yi gba gbogbo aye ti Poland gba loni. Ile-Oba Poland je didasile ni 1025, ni odun 1569 o bere long ajosepo pipe pelu Grand Duchy of Lithuania nipa titowobo Isokan ilu Lublin, to sedasile Ajoni Polandi ati Lithuania.
Ajoni yi wo ni 1795, be sini Poland je pipin larin Ile-Oba Prussia, Ile-Oluoba Rosia, ati Austria. Poland pada gba ilominira ni Igba Oselu Keji Poland ni 1918, leyin Ogun Agbaye Akoko, sugbon o je didurolori latowo Jẹ́mánì Nazi ati Isokan Sofieti nigba Ogun Agbaye Keji. Poland pofo emin awon eniyan toju egbegberun 6 lo ninu Ogun Agbaye Keji, o bere lekansi gege bi orile-ede Olominira awon Ara ile Poland larin Blok Ilaorun labe olori Sofieti.
Nigba awon Ijidide odun 1989, ijoba komunisti wolule leyin re Poland di "Oselu Keta Poland" pelu ofin ibagbepo. Poland je orile-ede onisokan, to je idipo awon ipinle merindilogun (Pólándì: [województwo] error: {{lang}}: text has italic markup (help)). Poland je ikan ninu Isokan Europe, NATO, Agbajo awo Orile-ede, Agbajo Idunadura Agbaye, ati Agbajo fun Ifowosowopo Okowo ati Idagbasoke (OECD).

![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads