Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: Presidente de Angola) ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba ní orílẹ̀-èdè Àngólà. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ tí wọ́n gbàtọ́ ní ọdún 2010 ṣe sọ, ipò alákóso àgbà jẹ́ píparẹ́; agbára aláṣẹ bọ́ sí ọwọ́ áárẹ.
Ìgbà ẹ̀mejì fún ọdún márùún ní ààrẹ le fi wà ní ipò.
Ní Osù Kínní ọdún 2010 ni Iléìgbìmọ̀ Aṣòfin fọwọ́sí òfin-ìbágbépọ̀ tuntun, lábẹ́ òfin yìí, olórí ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú tó ní iye ìjókòó tó pọ̀ jùlọ ní iléaṣòfin ni yíò di ààrẹ, kò ní jẹ́ dídìbòyàn tààrà látọwọ́ àwọn aráàlú.[2]
João Lourenço ni Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà lọ́wọ́lọ́wọ́, ó bọ́ sí orí ipò ní 26 September 2017.
Remove ads
Àtòjọ àwọn ààrẹ ilẹ̀ Àngólà (1975–d'òní)
Ẹ tún wo
- Àngólà
- Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Àngólà
- Alákóso Àgbà ilẹ̀ Àngólà
- Àtòjọ àwọn Alákóso Àgbà ilẹ̀ Àngólà
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads