Pretoria

From Wikipedia, the free encyclopedia

Pretoriamap
Remove ads

Pretoria je ilu kan ni apaariwa ni Igberiko Gauteng, ni orile-ede Guusu Afrika. O je ikan larin awon ilu oluilu meta, oun ni ibujoko ijoba wa (amojuto) ati de facto oluilu orile-ede; awon yioku ni Cape Town, ibujoko ile asofin, ati Bloemfontein, ibujoko onidajo.

Quick facts Country, Province ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads