Nọ́mbà àkọ́kọ́

From Wikipedia, the free encyclopedia

Nọ́mbà àkọ́kọ́
Remove ads

Ninu Ìmọ̀ Ìṣirò nọ́mbà àkọ́kọ́ (prime numbers) ni a si àwọn nomba adabaye (natural numbers) tí wọn ní nọmba ádábá méjí péreé tí a lè fí pín wọn dọ́gba, éyí ní nọmbaa 1 atí nọmba ákọkọ fún árá rẹ. Áwọn nọmba ákọkọ pọ tó bẹẹ tó fí jẹ wípé wọn kò lòpin gẹgẹe bí Efklidi ṣé fihàn ní ọdúnn 300 K.J (kia to bi Jesu, K.J). Nọmba ó 0 ati ọ̀kan 1 kì ṣé nọmba akọkọ.

Thumb
Quick facts Àwọn mathematiki, Basic ...

Bí àwọnon nọmba akọkọ ṣé

ẹètárá wọn wí íi yi : 2, 3, 5, 7, 11, 13, 17, 19, 23, 29, 31, 37, 41, 43, 47, 53, 59, 61, 67, 71, 73, 79, 83, 89, 97, 101, 103, 107, àtí, and 113

Nọmba 2 (íkèji)

í

i

íó

Remove ads

Nomba Akoko gege bi baba awon ááoíba ọdabÁ

IpóleùseAbagbo Isesiro la kale pe gbogbo nọ́mbà odidi (integers) apa otun ti won tobi ju 1 lo se ko sile gege bi isodipupo nomba akoko kan tabi jubelo ni ona kan pato. Fun apere a le ko:


Remove ads

Gbogbo Awon Nomba Akoko

Awon nomba akoko ko ni ye. Eyi ti je fifihan lopolopo ona. Eni akoko to koko fi eyi han ni Efklidi. Bi o se fi han ni yi:

E je ki a so pe awon nomba akoko to l'opin (finite) kan wa. E je ki a pe awon nomba wonyi ni m. Se isodipupo gbogbo m, ki o si se aropo re pelu okan (nomba Efklidi). Nomba esi ti ri ko se pin pelu ikojopo number akoko kankan t'olopin, nitoripe bi a ba se pin to okan yio seku, be sini okan ko se pin pelu nomba akoko. Nipa bayi, tabi ki o je nomba akoko fun ra ara re tabi ki o se pin pelu nomba akoko miran ti ko si ninu ikojopo to l'opin. Botiwulekaje, a gbudo ni nomba akoko ti yio je m + 1.
Remove ads
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads