Quett Masire

From Wikipedia, the free encyclopedia

Quett Masire
Remove ads

Quett Ketumile Joni Masire, GCMG (ojoibi July 23, 1925 ni Kanye, Botswana) je oloselu ati Aare ikeji orile-ede Botswana lati 1980 de 1998, o je omo egbe oloselu Egbe Toseluarailu Botswana. Nigba to kosesile ni 1998, Festus Mogae to je Igbakeji Aare ropo re lati di Aare ile Botswana keta.

Quick facts 2nd Aare ile Botswana, Asíwájú ...



Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads