Rabiu Kwankwaso

Olóṣèlú Naijiria From Wikipedia, the free encyclopedia

Rabiu Kwankwaso
Remove ads

Rabi'u Musa Kwankwaso FNSE (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀jilelogun oṣù kewa ọdún 1956) jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Kano lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni gomina Ipinle Kano tele ri.[1][2]

Quick facts Asíwájú, Arọ́pò ...

Ni odún 2022,ni won yan Rabiu Kwankwaso gẹ́gẹ́ bi olùdíje fun aare orílẹ̀ èdè Naijiria ti odun 2023 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People's Party.[3][4][5][3]

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads