Rashidi Yekini

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Rashidi Yekini (23 October 1963 – 4 May 2012) je agbaboolu-elese, elege-ara lowo iwaju omo ile Naijiria. O je eni to gba boolu metadinlogoji Sonu awon nigba ti o n gba boolu fun egbe agbaboolu Vitória de Setúbal ni orile ede potogi gege bi akoko omo orile ede olominira ile Naijiria ti yoo koko gba iru ami ayo bee wole. Bakan naa, lo run soju orile-ede re niniu oniruuru ifesewonse paapaa julo idije ife-agbaye [[(football)| world cups][ ni eyi ti o tun ti gba ami ayo kan soso akoko wole ti eyi si je ami-ayo akoko iru re to orile-ede naa too koko gba wole ninu idije naa. Won fi ami eye eni ti o mo boolu gba julo nile Adulawo | African footballer of the year da lola ni odun 1993.

Quick facts Personal information, Ọjọ́ ìbí ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads