STS-7

From Wikipedia, the free encyclopedia

STS-7
Remove ads

STS-7 je iranlose Oko alobo Ofurufu NASA, eyi ni iranlose ti Oko alobo Ofurufu Challenger lo lati gbe opo satelaiti lo si oju ofurufu. Oko na gbera lati Kennedy Space Center ni 18 June 1983, o si bale si Edwards Air Force Base ni 24 June. STS-7 ni iranlose oko alobo keje ati iranlose keji Challenger. Bakanna o tun je ifoloke ofurufu akoko Amerika to ni obinrin arinlofurufu.

Quick facts Statistiki ìránlọṣe, Orúkọ ìránlọṣe ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads