Ìjẹ́ẹ̀rí
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Shahada tabi ìjẹ́ẹ̀rí (Arabic: الشهادة aš-šahāda audio (ìrànwọ́·ìkéde)) (lati oro-ise [] error: {{lang}}: no text (help) šahida, "o jeri"), túmọ̀ sí "láti mo àti gbagbo láìsí ìfura, bíi jíjẹ́ẹ̀rí"; ó jẹ́ ọ̀kan nínú awon opo marun islam. Shahada ni ọ̀kan ìgbàgbọ́ nínú okan Allahu ta'âlâ àti gba Muhammad gẹ́gẹ́ bí ojise Olorun. Èyí yi ni pé:
- lâ ilâha illallâh, Muḥammadur rasûlullâh (ni Larubawa)
- Kò sí Ọlọ́run mìíràn àfi Ọlọ́run, Muhammad sì ni Òjíṣẹ́ Ọlọ́run (ni Yoruba)
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads