Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis
Remove ads

Ọkọ̀-ayára Òfurufú Atlantis ti o ti lo si inu ofurufu lati nnkan bi ose meji ni o pada si ile aye ni Edwards Airforce Base, California, U.S.A. ni oni ojo Ketalelogun osu kefa odun 2007. Gbogbo awon mejeeje ti won wa ninu re ni won ba a de. Sunita Williams naa ti gunle si ile aye. Oun ni obinrin ti o pe ju ni oju ofurufu. Ojo marundinlogowaa (195 days) ni o gbe ni oju ofurufu. Oun naa ni obinrin ti o rin ni oju ofurufu ju.

Quick facts AtlantisOV-104, OV designation ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads