Spẹ́ktróskópì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Spẹ́ktróskópì
Remove ads

Spẹ́ktróskópì ni iwadi ibase larin ohun-elo ati okun-inu titanka.[1][2] Spektroskopi bere ninu iwadi itanna fifojuri to fonka gegebi ìbú ìlàrúrú rẹ̀, f.a., latowo prísímù. Leyin atigba yi oye-ona yi gbale lati kan gbogbo ibase to ni okun-inu itanyindinyindin gegebi itori ibu ilaruru tabi frikuensi. Awon data spektroskopi unsaba je fifihan pelu spektrumu.

  1. , doi:10.1351/pac198658121737 Missing or empty |title= (help)
Thumb
Àwòrán Spiritusflamme mit spektrum.
Remove ads
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads