Tsad

From Wikipedia, the free encyclopedia

Tsad
Remove ads

Chad (Faransé: Tchad, Lárúbáwá: تشاد Tshād), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Chad, je orile-ede tileyika ni arin Afrika. O ni bode pelu Libya ni ariwa, Sudan ni ilaorun, orile-ede Arin Afrika Olominira ni guusu, Kameroon ati Naijiria si guusuiwoorun, ati Nijer si iwoorun. Nitori ijinna re si okun ati asale to gbabe ka, Tsad je mimo bi "Okan Kiku Afrika" ("Dead Heart of Africa").

  1. Central Intelligence Agency (2009). "Chad". The World Factbook. Archived from the original on April 24, 2020. Retrieved January 28, 2010.
  2. "Chad". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.
Quick Facts Republic of Chad [République du Tchad] error: {{lang}}: text has italic markup (help)جمهورية تشاد ‎Jumhūriyyat Tshād, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Remove ads
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads