Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
Remove ads

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá ti a mo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, UK tabi Britani jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Europe. Nínú bodè rẹ̀ ni a ti rí erékùsù Brítánì Olókìkí, apá ìlàoòrùn-àríwá erékùsù Irẹlandi àti ọ̀pọ̀ àwọn erékùsù kékéèké. Irẹlandi Apáàríwá nìkan ni apá Ilẹ̀ọba Ìsọ̀kan tó ní bodè mọ́ oríilẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Irẹlandi.

Quick facts Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì ApáàríwáUnited Kingdom of Great Britain and Northern Ireland, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads