Ùráníọ̀m

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ùráníọ̀m
Remove ads

Ùráníọ̀m tabi Uranium je apilese kemika onide bi fadaka funfun ninu eseese aktinidi ti tabili igba to ni nomba atomu 92. O ni ami-idamo kemika U. Atomu uraniom kan ni 92 awon protoni 92 ati awon elektroni 92.

Quick facts Uranium, Pípè ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads