Václav Havel
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Czech From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Václav Havel (Àdàkọ:IPA-cs) (5 October 1936 – 18 December 2011) je Tseki olukereitage, alaroko, alakitiyan ati oloselu. Ohun ni eni ikewa ati to gbeyin bi Aare ile Czechoslovakia (1989–92) ati eni akoko bi Aare ile Tseki Olominira (1993–2003). O ti ko ere itage to ju ogun lo ati awon iwe miran ti won ti je yiyiledepada kakiriaye. O gba Eso Aare fun Ominira ti Amerika, Eso Ominira Filadelfia, Enioto ile Kanada, ati Olusoju Ebun Eriokan. Bakanna ni 2005 o je didiboyan bi eni omowe 4th nini ibo gbogbo aye ti iwe olosoosu Prospect Magazine se larin awon omowe 100 olokiki julo.[1]


![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads