Wilhelm Röntgen

From Wikipedia, the free encyclopedia

Wilhelm Röntgen
Remove ads

Wilhelm Conrad Röntgen tàbí Wilhelm Roentgen tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1845, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1923 (27th March 1845 – 10 February 1923) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Jemani onímọ̀ físíìsì, tí ó ṣẹ̀dá àti àwárí iran oninagberingberin ninu awon iye igun iru a mo loni si x-ray tabi Röntgen rays lọ́dún 8 November 1895, tí oríire rẹ̀ sọ ọ́ di ẹni àkọ́kọ́ tó gba Ẹ̀bùn is Nobel nínú Físíìsì ni 1901.[1]:1

Quick Facts Ìbí, Aláìsí ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí ọ̀tọ̀

Wikiquote logo
Wikiquote logo
Nínú Wikiquote a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́:

Àdàkọ:Wikisource author

Àdàkọ:Nobel Prize in Physics Laureates 1901-1925

Àdàkọ:Authority control

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads