Deep Roy
From Wikipedia, the free encyclopedia
Gurdeep Roy (orúko ibí rẹ̀ ni Mohinder Purba; tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù Kejìlá ọdún 1957), tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ sí Deep Roy, jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Kenya àti Britain. Nítorí pé ko ga tàrà(gíga rẹ̀ ko ju 132 centimetres (4 ft 4 in) lọ,[1] ó ma ń sábà kópa àwọn ènìyàn tí kò ga nínú àwọn eré, bí àpẹẹrẹ gẹ́gẹ́ bi Teeny Weeny nínú The NeverEnding Story àti Oompa-Loompas nínú Charlie and the Chocolate Factory, Keenser in Star Trek, àti nínú àwọn eré bi The X-Files, Doctor Who, àti Eastbound & Down.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orúkọ míràn ...
Deep Roy | |
---|---|
Roy ní Florida SuperCon ti ọdún 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Mohinder Purba 1 Oṣù Kejìlá 1957 (1957-12-01) (ọmọ ọdún 66) Nairobi, Kenya Colony |
Orúkọ míràn | Gurdeep |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1976–present |
Height | Àdàkọ:Infobox person/height |
Olólùfẹ́ | Millie Farris (m. 2014) |
Close