Oṣù Kejìlá
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Kàlẹ́ndà31Ọjọ́Bẹ̀rẹ̀NíỌjọ́ Àìkú
Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá |
Osù Ọ̀pẹ nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run Yorùbá ni ó jẹ́ oṣù Kejìlá nínú ònkà oṣù ojú ọ̀run ti àwọn (Gẹ̀ẹ́sì) tí wọ́n pè ní December Ọjọ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n ni ó wà nínú oṣù yí.
Osù December ni awọn gẹ̀ẹ́sì fa orúkọ rẹ̀ yọ látara ọ̀rọ̀ ""decem" (tí ó túmọ̀ sí ten) nítorí wípé òun gaan ni oṣù kẹwàá ọdún nínú kalẹ̀dà tí àwọn calendar of Romulus c. 750 BC tí ìbẹ̀rẹ̀ oṣù tiwọn sì bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹta ọdún. Àwọn oṣù tókù kò ti sí tẹ́lẹ̀, amọ́ wọ́n ṣàfikún oṣú kínní ati oṣù kejì kun tí December sì dá dúró ní tirẹ̀. [1]