Àwùjọ Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwùjọ Áfríkà jẹ́ àpapọ̀ àwọn àwùjọ tí ó wá láti Áfríkà, pàápàá jùlọ àwọn tí ó wà ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà lọ́wọ́lọ́wọ́.[36] Wọ́n ma ń fi ọ̀rọ̀ náà ṣàpèjúwe àwọn tí ó aláwò dúdú ní Ìwọ oòrùn àti Àrin Áfríkà tí àwọn òyìnbó kó lẹ́rú ní àárín centuri kẹríndínlógún sí ọ̀kàndínlógún, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹrú yìí ni wọ́n kọ́ lọ àwọn orílẹ̀-èdè bi Brazil, Amẹ́ríkà, àti Haiti.[37][38] Wọ́n tún le fi ọ̀rọ̀ náà ṣàpèjúwe àwọn ọmọ Àríwá Áfríkà tí won kìí se aláwò dúdú ṣùgbọ́n tí wón kó lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè míràn.[39]
Map of the African Diaspora in the World.svg | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Regions with significant populations | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
| ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Èdè | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Lingua franca: English (American and Caribbean), French (Canadian, Haitian), Haitian Creole, Spanish, Portuguese, Papiamento and Dutch | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ẹ̀sìn | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Christianity, Islam, Traditional African religions, Afro-American religions |
Ní ayé ìsinsìnyí, wọ́n ń fi ọ̀rọ̀ náà ṣàpèjúwe àwọn ènìyàn tí ó kó láti Áfríkà lọ sí orílẹ̀ èdè míràn.[40] Aájò African Union (AU) sọ wípé àwùjọ Áfríkà jẹ́: "àwọn ọmọ Áfríkà tí kò gbé ní ilẹ̀ míràn yàtò sí ilẹ̀ Áfríkà, tí wón sì ṣe tán láti gbé ilẹ̀ Áfríkà lárugẹ.[41]