Ọjọ́ Àbámẹ́ta
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ọjọ́ Àbámẹ́ta tabi Satide tí wọ́n tún ń pe ní diēs Sāturnī ("Saturn's Day") je òpin ọjọ́ ọ̀sẹ̀ tí ó wà láàrín ọjọ́ Ẹtì àti Ọjọ́ Àìkú. [1][2]
Ọjọ́ Àbámẹ́ta ni ọjọ́ keje tí ó kẹ́yìn nínú ọjọ́ ọ̀sẹ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |