From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Other uses Àdàkọ:Pp Àdàkọ:Lead too short
Ọṣẹohun èlò tí a ń lò láti fi fọ ohun tí ó bá ṣeé ṣe imọ́ tótó, gẹ́gẹ́ bí imọ́ tótó ara, aṣọ, ilẹ̀, abọ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ohun èlò yí lè jẹ́ ohun tí a ń lò nínú ilé tàbí ní ìta, ilé tàbí ilé iṣẹ́. Bí a bá lo ọṣẹ́ fún imọ́ tótó, ó ma ń yọ ìdọ̀tí òun ẹ̀gbin kúrò nínú ohun tí a bá fi ọṣẹ fọ̀ tàbí kí ó mú àdínkù bá irúfẹ́ ìdọ̀tí bẹ́ẹ̀.[1] A ma ń lo ọṣẹ fún imọ́ tótó pẹ̀lú ìrànọ́wọ́ omi, nítorí ọṣẹ nìkan kò ṣeé dá lò láti fi fe nkan.
Láyé àtijọ́, ọṣẹ ìgbámú ni gbogbo ènìyàn mọ̀ tí wọ́n sì ń lò. Àmọ́ laye òde òní, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ti jẹ́ kí á ma lo ọṣẹ olómi, àti ọṣẹ òníyẹ̀fun. [2], Ọmọ ènìyàn ti ń lo ọṣẹ láti ayébáyé fún ìṣe ìmọ́ tótó àyíka òun ara wọn.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.