![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/67/ADO_AWAYE_SUSPENDED_LAKE_IN_ISEYIN_OYO_STATE_NIGERIA.jpg/640px-ADO_AWAYE_SUSPENDED_LAKE_IN_ISEYIN_OYO_STATE_NIGERIA.jpg&w=640&q=50)
Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìséyìn
agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ / From Wikipedia, the free encyclopedia
Iseyin jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Nàìjíríà. ó jẹ̀ dede Ariwa ilẹ Ibadan. Ìlú náà ní onka ènìyàn tí o to 236,000 gẹ́gẹ́ bí àjọ agbaye ti fi múlẹ ní ọdún 2005, eleyii tí o padà le ti ọ sí di 362,990 ni ọdún 2011 ti ọ sí ni àlà ilé tí o jẹ,[1][2]
Quick Facts Iseyin Iseyin-Okeogun, Country ...
Iseyin Iseyin-Okeogun | |
---|---|
![]() | |
Motto(s): Iseyin oro, oro ọmọ ebedi mọkọ | |
Coordinates: 7°58′N 3°36′E | |
Country | ![]() |
State | Oyo State |
Government | |
• Local Government Chairman and the Head of the Local Government Council | Muftau Osuolale (PDP) |
Area | |
• Total | 702 sq mi (1,819 km2) |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
National language | Yorùbá |
Close