Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìpínlẹ̀ Oyo jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ Mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yí wà ní Ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí olú-ìlú rẹ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn, tí olú-ìlú rẹ̀ sí jẹ́ ìlú kẹta tí ó lérò púpò julọ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí o si figbakan je ìlú Kejì tó lérò púpò julọ ní Áfríkà ri. A dá ìpínlè Ọ̀yọ́ sílè ní ọjọ́ kẹta oṣù kejì ọdún 1976. Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ ìpínlè kaarun ti èrò pọ julọ sí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ | |
---|---|
Nickname(s): | |
Location of Ọyọ State in Nigeria | |
Coordinates: 8°00′N 4°00′E[1] | |
Country | Nigeria |
Date created | 3 February 1976 |
Capital | Ibadan |
Government | |
• Governor[2] | Oluwaseyi Makinde (PDP) |
• Deputy Governor | Rauf Olaniyan |
• Senators | Abdulfatai Buhari Kola Balogun Teslim Folarin |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 28,454 km2 (10,986 sq mi) |
Population (2006)[3] | |
• Total | 5,580,894[4] |
GDP | |
• Year | 2007 |
• Total | $29.8 billion[5] |
• Per capita | $2,666[5] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-OY |
HDI (2016) | 0.440[6] · 22nd of 36 |
Website | oyostate.gov.ng |
Púpọ̀ nínu àwọn ará ìpínlè Ọ̀yọ́ jẹ́ Yorùbá, ti èdè Yorùbá sì jẹ èdè tí wọ́n n sọ julọ ní ìpínlè náà.
Ṣèyí Mákindé jẹ́ gómìnà ìpínlẹ́ Ọ̀yọ́.
Ìpínlẹ́ Ọ̀yọ́ ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n. Awon ni:(E tun wo awon AII Naijiria)
Awọn ilé ẹ̀kọ́ gíga wọ̀nyí ni wón wa ni ìpínlè Oyo;[7]
Commissioner/Officer | Ministry/Office |
---|---|
Engr. Oluwaseyi Makinde | Governor |
Bayo Lawal | Deputy Governor |
Adebo Ogundoyin | Speaker of the State House of Assembly |
Mrs. Olubamiwo Adeosun | Secretary to the State Government |
Hon. Segun Ogunwuyi | Chief of Staff |
Mr Akinola Ojo | Commissioner for Finance |
Hon. Temilolu Ashamu | Commissioner for Energy & Mineral Resources |
Mrs Amidat O. Agboola | Head of Service |
Chief Mikail Adebayo Lawal | Commissioner for Local Government & Chieftaincy Affairs |
Prof. Oyelowo Oyewo | Attorney-General & Commissioner for Justice |
Nípa didrarí Ìjọba ipinlẹ naa, Gómìnà tiwantiwa ní wọn ó yàn láti kè darí àti láti lè sisẹ́ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ ilé Ọ̀yọ́. Olú ilé Ìpínlẹ̀ jẹ́ Ìpínlè Ìbàdàn.[10]
Iṣé oko tàbí isẹ́ ọ̀gbìn jẹ́ Olú iṣẹ́ kàn pàtó tí àwọn ará ilè Ọ̀yọ́ máa ń ṣe. Ojú ojó àti afẹ́fẹ́ ìlú Ọ̀yọ́ jẹ́ òun kàn tí ó jẹ́ kí àwọn oún ọ̀gbìn wà lọ́pọ̀ yanturu, àwọn náà wà ní ọlọ́kan- ọ̀jọ̀ kan, lórísirísi bí: Iṣu, Àgbàdo, Ẹ̀gẹ́, Ọ̀gẹ̀dẹ̀, Kòkó, Epo pupa, Ẹ̀pa Kàsú,. Bẹ́ẹ̀ náà síni, àwọn Ìjọba ní oko ògbìn ní àwọn àgbègbè bìí, Ìséyìn, ìpàpó, Ìlọrà, Ògbómọ̀ṣọ́, Èrúwà, Iresaadu, Ìjàìyè, Akúfó àti Lálúpọn. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ amọ̀ wà, Kaolin àti aquamarine. Àwọn Oko ẹran nlánlá tún wà ní Ṣakí, Fáṣọlá àti Ibàdàn, oko ìfúnwàrà ni Monatan ní Ìbàdàn àti ètò Ìdàgbàsókè Ọ̀gbìn ní ìpínlè Ọ̀yọ́ tí olú ilé iṣé é wà ni Ṣakí. Àìmọye Ilé isé ọ̀gbìn tió jẹ́ tòkè òkun àti tiwantiwa ní ó wà ní ìpínlè náà.[{citation needed|date=December 2022}}
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.