Bello Mohammed Tukur
Omo ile igbimo asofin agba Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Bello Mohammed Tukur jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.[1][2][3][4][5]
Quick Facts Aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, Asíwájú ...
Bello Mohammed Tukur | |
---|---|
Aṣojú àárín Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Jubril Aminu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Close