From Wikipedia, the free encyclopedia
Ernesto "Che" Guevara (Pípè: [ˈtʃe geˈβaɾa][4]; June 14,[1] 1928 – October 9, 1967), to gbajumo bi El Che tabi lasan bi Che, je omo ile Argentina to je olujidide Marksisti, oniwosan, oludako, omowe, olori guerrilla, diplomati, oludero ologun, ati eni pataki Ijidide Kuba. Lati igba to to ailaisi, aworan re ti di ami=idamo olodiasa kakiri ati ami eye lagbaye larin asa agbajumo.[5]
Che Guevara | |
---|---|
"Guerrillero Heroico" Che Guevara at the La Coubre memorial service. Taken by Alberto Korda on March 5, 1960. | |
Ọjọ́ ìbí: | June 14, 1928[1] |
Place of birth: | Rosario, Argentina |
Ọjọ́ aláìsí: | October 9, 1967 ọdún 39) | (ọmọ
Place of death: | La Higuera, Bolivia |
Major organizations: | 26th of July Movement, United Party of the Cuban Socialist Revolution,[2] National Liberation Army (Bolivia) |
Religion: | None[3] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.