Cissy Houston
From Wikipedia, the free encyclopedia
Emily "Cissy" Houston (oruko idile Drinkard; ojoibi September 30, 1933)[3] je akorin soul ati gospel ara Amerika. Houston gba Ebun Grammy ni emeji fun awon orin re. Houston ni mama akorin Whitney Houston, iya-iya fun Bobbi Kristina Brown, aunti fun awon akorin Dionne ati Dee Dee Warwick, ati ibatan akorin opera Leontyne Price.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Cissy Houston | |
---|---|
Houston in 1975 | |
Ọjọ́ìbí | Emily Drinkard 30 Oṣù Kẹ̀sán 1933 (1933-09-30) (ọmọ ọdún 90)[1][2] Newark, New Jersey, U.S. |
Iṣẹ́ | Singer & actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1938–present |
Olólùfẹ́ | Freddie Garland (m. 1955–1957) John Houston Jr. (m. 1959–1990) |
Àwọn ọmọ | 3; including Gary and Whitney |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals (soprano) |
Labels |
|
Associated acts |
|
Close
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |