Kúbà
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kúbà tabi Orile-ede Olominira ile Kuba (pípè /ˈkjuːbə/ ( listen); Spánì: [República de Cuba] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [reˈpuβlika ðe ˈkuβa] ( listen)) je orile-ede erekusu ni Karibeani. Orile-ede Kuba ni erekusu Kuba gbangba, Isla de la Juventud, ati awon sisupapo-erekusu.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kúbà Republic of Cuba [República de Cuba] error: {{lang}}: text has italic markup (help) (Híspánì)
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Havana |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Spani |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 65.05% ènìyàn Funfun (Spani, àwọn yìókù), 10.08% ọmọ Afrika, 23.84% Mulatto ati Mestizo[3] |
Orúkọ aráàlú | Cuban |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè sósíálístì àwọn òsìṣẹ́, gbígbájọ bíi orílẹ̀-èdè olómìnira aparapọ̀ àti tòṣèlúaráìlú[4] Orílẹ̀-èdè kómúnístì[5] |
• Ààrẹ | Miguel Díaz-Canel |
• Igbákejì Ààrẹ̀ Àkọ́kọ́ | Salvador Valdés Mesa |
Raúl Castro | |
Ìlómìnira kúrò lọ́dọ̀ Spein | |
• Fífilọ́lẹ̀ | 10 Oṣù Kẹ̀wá, 1868 |
• Fífilọ́lẹ̀ bíi olómìnira | 20 Oṣù Kárún, 1902 kúrò lódò U.S |
• Ìjídìde Kúbà | 1 Osú Kínní, 1959 |
Ìtóbi | |
• Total | 109,886 km2 (42,427 sq mi) (105th) |
• Omi (%) | negligible[6] |
Alábùgbé | |
• 2008 estimate | 11,236,444[7] (75th) |
• 2002 census | 11,177,743[7] |
• Ìdìmọ́ra | 102/km2 (264.2/sq mi) (97th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $111.1 billion[8] (62nd) |
• Per capita | $9,700 (86th) |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $65.67 billion[9] (63rd) |
• Per capita | $5,844 (80th) |
HDI (2007) | 0.863[10] Error: Invalid HDI value · 51st |
Owóníná | Pẹ́só Kúbà(CUP )Cuban convertible peso[11] (CUC) |
Ibi àkókò | UTC-5 |
• Ìgbà oru (DST) | UTC-4 ((March 11 to November 4)) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | +53 |
Internet TLD | .cu |
Havana ni ilu titobijulo nibe ati oluilu re. Santiago de Cuba ni ilu keji totobijulo.[12][13]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.