Èdè Spéìn

From Wikipedia, the free encyclopedia

Èdè Spéìn
Remove ads

Èdè Sípéènì (español tàbí castellano) jẹ́ èdè ní orílẹ̀-èdè Sípéènì, wọ́n sì sọ èdè yìí púpọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè Apá Gúúsu Amẹ́ríkà. Èdè Sípéènì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Rómáńsì, àwọn èyí tí wọ́n fà yọ láti inú èdè Látìnì.

Quick Facts Ìpè, Sísọ ní ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads