From Wikipedia, the free encyclopedia
Damon Kyle Wayans Sr. ( /ˈdeɪmən ˈweɪ.ənz/;[1] ojoibi September 4, 1960)[2] je alawada, osere, olukowe, ati atokun ara Amerika, ati ikan ninu awon Ẹbí Wayans. Wayans sise bi alawada ati osere ni gbogbo odun awon ewadun 1980, nigba to kopa ninu ere alawada Saturday Night Live.
Damon Wayans | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Damon Kyle Wayans |
Ìbí | 4 Oṣù Kẹ̀sán 1960 New York City, U.S. |
Medium |
|
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdè | American |
Years active | 1981–present |
Genres | Observational comedy, black comedy, political satire |
Subject(s) |
|
Ninu ere alawada In Living Color gangan ni ebun re ti yo jade gege bi olukowe ati alawada lati 1990 di 1992. Lati igba na o ti kopa ninu filmu ati ere telifisan opolopo bii The Last Boy Scout ati Major Payne, ati ere telifisan My Wife and Kids. Lati 2016 de 2019, o sere gegebi Roger Murtaugh ninu ere telifisan Lethal Weapon.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.