Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
David Van Cortlandt Crosby (tí wón bí ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ, ọdún 1914, tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún, ọdún 2023)[1]jẹ́ akọrin àti olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ohun tí ó kọ́kọ́ sọ ọ́ di gbajúmọ̀ ni jíjẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹ "the Byrds." Crosby ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn àwo-orin adáṣe mẹ́jọ, bótilẹ̀jẹ́pé lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan ni, lákòókò iṣẹ́ rẹ̀. Àwọ rẹ̀ kan tí ó ṣìfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1197 ni àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Tí MO Bá Le Rántí Orúkọ Mi Nìkan (If I Could Only Remember My Name)."[2]
ẹ̀yà | akọ |
---|---|
country of citizenship | Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà |
name in native language | David Crosby |
orúkọ àbísọ | David Van Cortlandt Crosby |
orúkọ àfúnni | David |
orúkọ ìdílé | Van Cortlandt, Crosby |
ọjó ìbí | 14 Oṣù Ògún 1941 |
ìlú ìbí | Los Angeles |
ọjó ikú | 18 Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ 2023 |
ibi ikú | Santa Ynez |
òùnfà ikú | Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 |
bàbá | Floyd Crosby |
ìyá | Aliph Van Cortlandt Whitehead |
ègbón àti àbúrò | Ethan Crosby |
ọmọ | James Raymond, Beckett Cypher |
Ebí | Van Cortlandt family, Van Rensselaer family |
native language | gẹ̀ẹ́sì |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì |
writing language | gẹ̀ẹ́sì |
ẹ̀kà iṣẹ́ | orin, music composing, guitar performance, lyrics, composed musical work |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Cate School, Santa Barbara City College |
work period (start) | 1964 |
work period (end) | 2023 |
medical condition | type 2 diabetes |
discography | David Crosby discography |
genre | rock music, folk rock, country rock, jazz fusion |
record label | Atlantic Records, A&M Records, Rhino |
award received | MusiCares Person of the Year, Rock and Roll Hall of Fame |
official website | https://davidcrosby.com/ |
copyright representative | SESAC |
copyright status as a creator | works protected by copyrights |
facial hair | walrus moustache |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.