Jihad ti Usman dan Fodio
From Wikipedia, the free encyclopedia
Jihad ti Usman dan Fodio jẹ ija ẹlẹsin-ologun to waye in Orilẹ ede Naijiria ati ilu Cameroon. Ogun naa bẹrẹ nigba ti a lè Usman Dan Fodiyo, ogbon tarigi onimọ ẹsin islam ati olukọ kuro ni Gobir, eleyi ṣẹlẹ lati ọwọ ọkan ninu akẹẹkọ rẹ Ọba Yunfa[1].[2]
Quick Facts Ìgbà, Ibùdó ...
Jihad of Usman dan Fodio | |||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|
Part of the Fula jihads | |||||||
The Sokoto Sultanate (Sokoto Empire) in the reign of sultan Ahmadu Rufai, established after the Jihad led by Shaikh Usman bin Fodiyo. | |||||||
| |||||||
Àwọn agbógun tira wọn | |||||||
Sokoto Caliphate Support: Kel Ayr |
Hausa Kingdoms
| ||||||
Àwọn apàṣẹ | |||||||
|
|
Close
Usman Dan Fodiyo ṣè agbatẹru awọn ologun ẹsin islam lati ṣè jihad lori afin ilẹ hausa to wa ni ariwa órilẹ ede Naijiria. Awọn ologun Usman Dan Fodiyo Kapa ọpọlọpọ ilẹ hausa nibi tan ti gba koso lori Gobir ni ọdun 1808 ti wọn si pa Yunfa. Ija yi lo yi sisi dida Sokoto Caliphate silẹ, eleyi lo pada di ọkan lara awọn ipinlẹ to tobi julọ ni ilẹ Afirica[3]. Aṣèyọri yi ló ṣipaya jihad óriṣiriṣi miran to pada waye ni apa Iwọọrun ilẹ Afrika.