Lagos Lagoon
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Lagos Lagoon jẹ́ omi ọ̀sà[1] tí ó bá Ìlú Èkó jorúkọ. Orúkọ yìí jẹ́ orúkọ Àgùdà tí ó túnmọ̀ sí "Omi ńlá" ní Èdè Àgùda, nítorí èyì "Lagos Lagoon" jẹ́ àpẹrẹ orúkọ ìbálú jórúkọ.
Lagos Lagoon | |
---|---|
Location | Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Coordinates | 6.5015814°N 3.5224915°E |
Lake type | lagoon |
Basin countries | Nàìjíríà |
Max. length | 50 km |
Max. width | 13 km |
Surface area | 6,354.7 km² |
Surface elevation | 0 m |
Islands | Lagos Island, Victoria Island |
Settlements | Èkó |
Gígùn ọ̀sà yìí ju àádọ́ta kìlómítà lọ, ó jìnà sí òkun pẹ̀lú fífè méjì sí márún, tí ó sì ní irà lẹ́bá etí ọ̀sà. Fífẹ̀ rẹ̀ tó bíi 6,354.7 km².[2] Ọ̀sà yìí tòrò níwọ̀nba, tí àwọn ọkọ̀ ojú omi nla tó ń gba ojú òkun kìí dàárú.
Ọ̀sà yìí jápọ̀ mọ́ Odò Ògùn àti Odò Ọsun.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.