![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/8/80/Lee_Grant_1967.jpg/640px-Lee_Grant_1967.jpg&w=640&q=50)
Lee Grant
From Wikipedia, the free encyclopedia
Lee Grant (orúkọ àbísọ ni Lyova Haskell Rosenthal tíwọ́n bí ní October 31, ní àárín 1920)[lower-alpha 1] jẹ́ òṣèré ilé Améríkà, Olùdarí Eré àti ẹni tí ó ń ṣe iṣé Documentary. Eré àkọkọ rẹ ní èyí tí o ṣe ọmọde tí ń Fẹ́wọ́ nínú eré Detective Story tí William Wyler ṣe Adarí eré náà ni 1951, àwọn tí wọn sì kópa náà ní Kiri Douglas àti Eleanor Parker. Ìkópa rẹ̀ ninu eré yìí ní ọ jẹ́ kí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí Best Supporting Actresses lati lẹ̀ gba Àmì Ẹ̀yẹ Akádẹ́mì/ Oscar, ó sí gbà àmi ẹ̀yẹ Best Actress ní Cannes film Festivals Award. Ní ọdún 1952, ó wá lára àwọn mẹwàá tí Hollywood yóò fún ọdún méjìlá. Amò leyin èyí ní ó máa ń ṣe awọn eré ìtàgè kékéékèké tàbí iṣé Olúkóni ní ìgbà náà. Èyí náà mú kí óun àti ọkọ rẹ̀ wà ní ìpínyà. Ní àsìkò yìí Grant ṣe awọn eré ìtàgè. Ní ọdún 1963 ní Hollywood tó pé pada láti lè tẹsiwaju nínú iṣẹ eré rẹ̀ . Ó tí kópa nínú eré mọ́kànlèládọ́rin eré ọlọ́sọ́ọ̀sẹ̀ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Peyton Place lati ọdún 1965 sí 1966, àwọn eré mìíràn tí ó jẹ́ Olú òṣèré ní "Valley of Dolls" àti "In the heat of the Night ní 1967, àti Shampoo ní 1975, èyí tí o sí gbà àmi ẹ̀yẹ Oscar fún eré náà. Ní ọdún 1964 ó gbà Àmi ẹyẹ́ "Onje" fún ìkópa rẹ̀ nínú eré "The Maids. Nígbà tí ó ń ṣe iṣé eré gbogbo wọnyi ó wà lára àwọn tí wọ́n yàn ní ẹ̀mẹfà láti gba àmì ẹ̀yẹ "Emmy" ní ọdún 1966 sí 1933, èyí tí ó sí gbà Ẹbùn àmì ẹ̀yẹ náà ní ẹ̀ẹ̀mejì. Ní ọdún 1986, ọ darí òun àkójọpọ̀ kan Documentary tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ "Down and Out ìn America" èyí tí ó wà ni ìsopọ̀ pẹlú Academy Awards for heat Documentary Feature, ní ọdún yẹn bákan náà ni ọ gba àmì ẹ̀yẹ Directires Guild Of America fún eré Nobody's Child.
Lee Grant | |
---|---|
![]() Grant in 1967 | |
Ọjọ́ìbí | Lyova Haskell Rosenthal October 31, during the mid-1920s[lower-alpha 1] (age 96–98). New York City, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Neighborhood Playhouse School of the Theatre Actors Studio |
Iṣẹ́ | Actress and director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1933–present |
Olólùfẹ́ | Arnold Manoff (m. 1951; div. 1960) Joseph Feury (m. 1970) |
Àwọn ọmọ | 2, including Dinah Manoff |