Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Brazil From Wikipedia, the free encyclopedia
Luiz Inácio Lula da Silva (Pípè ni Potogí: [luˈis iˈnäsjʊ ˈlulɐ dä ˈsiʊ̯vɐ]; ojoibi 27 October 1945), o gbajumo gege bi Lula,[1] ni Aare orile-ede Brazil lati 2003 titi 2011. A tún yàn sípò ààrẹ fún sáà kẹta ni odun 2022, tí à sì ṣe ìbúra-wọlé fun ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 2023. Oun ni Ààrẹ orílè-èdè Brazil lọ́wọ́ lọ́wọ́.
Luiz Inácio Lula da Silva | |
---|---|
35th President of Brazil | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 January 2023 | |
Vice President | Geraldo Alckmin |
Asíwájú | Jair Bolsonaro |
In office 1 January 2003 – 1 January 2011 | |
Vice President | José Alencar |
Asíwájú | Fernando Henrique Cardoso |
Arọ́pò | Dilma Rousseff |
Leader of the Workers' Party | |
In office 10 February 1980 – 15 November 1994 | |
Asíwájú | Position established |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹ̀wá 1945 Caetés, Brazil |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Partido dos Trabalhadores (PT) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Maria de Lurdes (1969-1971; Deceased) Marisa Letícia Rocco Casa (1974-2017) Rosângela Lula da Silva (2022-) |
Àwọn ọmọ | Fábio Luís Lurian Cordeiro Luís Cláudio Marcos Cláudio (Adopted) Sandro Luís |
Residence | São Bernardo do Campo |
Profession | Automotive worker Union organizer |
Signature |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.