MV Maersk Andaman
From Wikipedia, the free encyclopedia
MV Maersk Andaman (tẹ́lẹ̀tẹ́lè Maersk Alabama) jẹ́ ọkọ̀ ojú omi ẹlẹ́rù ti Maersk Line Limited tí ó wà ní ìmú ṣiṣẹ́ Waterman Steamship Corporation.[1] Ó ní àwọ̀ búlu tí ó fẹ́ mọ́ díẹ̀ pẹ̀lú ìrísí bi ti ọkọ̀ Maersk tókù láì wo tí àsíá ìforúkọsílẹ̀ wọn. Àwọn ajalèlókun jáagbà lẹgbẹ́ Somalia ní ọdún 2009, wọ́ sí mú àwọn atukọ̀ ẹ lati gba owó ìdásilẹ̀. Ìgbìyànjú mẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tò lati já ọkọ̀ náà gbà jásí pàbó lẹ́yìn ọdún náà ní ọdún 2010 àti 2011.[2]