Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Mary Tyler Moore (december 29, 1936 – January 25, 2017) jẹ́ òṣère ará ìlú Amẹ́rícà, olùdarí, àti alágbàwí àwùjọ. A mọ̀ọ́ sí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré The Dick Van Dyke Show (1961–1966) àti pàá pàá The Mary Tyler Moore Show (1970–1977), èyí tí "ó ṣe ìrànlọ́wọ́ láti fi túmọ àfojúsùn tuntun fún àwọn obìnrin ilẹ̀ amẹ́ríka"[1] àti "bẹ̀bẹ̀ sí olùgbọ́ tí ó dojúkọ ìṣòro tuntun ti ayé òde ".[2][3][4][5] Moore won ja wé seven Primetime Emmy Awards and three Golden Globe Awards.[6][7] Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ̀ Academy Award fún òṣèrébìnrin tó dára jù lọ fún fíìmù Ordinary People.[8][9][10] Moore kópa nínú fíìmù olórin, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Thoroughly Modern Millie. Moore jẹ́ àjàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn, elétò ìlera àti olùṣèwádìí.[11][12]
Mary Tyler Moore | |
---|---|
Moore in 1978 | |
Ọjọ́ìbí | New York City, U.S. | Oṣù Kejìlá 29, 1936
Aláìsí | January 25, 2017 ọdún 80) Greenwich, Connecticut, U.S. | (ọmọ
Resting place | Oak Lawn Cemetery, Fairfield, Connecticut, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Immaculate Heart High School |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1955–2013 |
Height | Àdàkọ:Infobox person/height |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 1 |
Signature | |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.