Ofada rice tàbí iresi Ofada jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ounjẹ Yoruba. Ó jẹ́ orúkọ tí wón fún iresi ti wọ́n gbìn ní ìlú Ofada ni agbègbè Obafemi Owode Ìpínlẹ̀ Ogun. Kò kín se ìlú Ofada nìkan ni wọ́n ti ń gbin. Wọ́n ma ń gbin ni gúúsù apá ìwọ oòrùn Nàìjíríà sugbon orúkọ ìlú náà ni wọn fun.[1][2][3] Wọ́n fi iresi Ofada se ọ̀pọ̀lọpọ̀ oúnjẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oúnjẹ yìí sì jẹ́ asepo. Àwọn nkan míràn ti wón fi kún àwọn asepo yìí kí se láti Nàìjíríà tàbí Áfríkà. Wọn ń gbin iresi Ofada ní ilè olómí.[4]

Thumb
Iresi Ofada (oke apa ọtun) pẹlu ọgede didin ati ẹran malu
Thumb
Iresi Ofada

Àwon Ìtókasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.