![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/62/White_Cat_Nursing_Four_Kittens_HQ.jpg/640px-White_Cat_Nursing_Four_Kittens_HQ.jpg&w=640&q=50)
Omu sise
From Wikipedia, the free encyclopedia
Omú Sísẹ̀ ṣe àpèjúwe ìtújáde wàrà láti àpò wàrà tí wọ́n ń pè ní Mammary Gland, àti ìgbà tí ìyá ọmọ bá ń fún ìyá ní wàrà mu ní èyí jẹ́. Ìlànà náà máa wáyé ní ọnà àrà ní ará ẹni tí ó bá jẹ́ obìnrin tàbí abo tí ó ti bàlágà.[1] ìlànà tí àwọn abo máa ń gbà fún àwọn ọmọ ní wàrà ní a ń pẹ̀ ni Ìtọ́mọ, bákan náà ni àwọn tí ó bá ń tọjú ni à ń pẹ̀ ní "Ìfọ́mọlọ́mú". Àwọn ọmọ ìkókó tí a ṣẹ̀sẹ̀ bí gan á máa mu wàrà láti inú ará wọn, èyí tí a lè pè ní colloquially tàbí "witch's milk"
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/62/White_Cat_Nursing_Four_Kittens_HQ.jpg/640px-White_Cat_Nursing_Four_Kittens_HQ.jpg)
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/c/cf/Lactating_Female_Coyote_-_cropped.jpg/640px-Lactating_Female_Coyote_-_cropped.jpg)
Ní ará àwọn ẹdá mìíràn tí ó wà, Ọmú ṣíṣẹ̀ jẹ́ àmì pé Ọmọ obìrin tàbí àbò tí ní oyún rí ni ìgbà kàn láyé rẹ, amò ní ara ẹ̀yà àwọn èèyàn àti àwọn ewúrẹ, èyí lẹ̀. Wáyé láì sí oyún rárá.[2][3] A lé sọ pé Gbogbo ọ̀sìn ni ó ní Orí Ọmú; yàtọ̀ sí àwọn ọ̀sìn tí wọ́n ń pẹ̀ ní "Monotremes", àwọn ọ̀sìn tí wọ́n máa ń yé ẹyin, èyí tí ó jẹ́ pé dípò ṣíṣẹ̀ wàrà láti ọmù, wàrà a máa jáde nínú ikú nípasẹ̀ ducts. Ọ̀sìn kan tí ó máa ṣé èyí tí ó sí jẹ́ Akọ ní Dayak Fruit bat tí ó jẹ́ Àdán tí a lè rí ní Apa gúúsù oòrùn Asia.
''Galactopoiesis'' jẹ́ ìtọ́jú ìselọ́pọ̀ wàrà. Ìpele yìí nílò Prolactin. Oxytocin jẹ́ ohun tí ó ṣe pàtàkì fún ṣíṣẹ̀ wàrà fún mímú àwọn ìkókó. [[Galactorrhea]] jẹ́ ìṣelọ́pọ̀ wàrà kò ní nǹkan ṣe pẹ̀lú ìtọ́mọ. Nítorí èyí lè wáyé láàrin àwọn ọ̀sìn yálà abo tàbí akọ èyí jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí àwọn àìsedédé Hòmónì (hormones) tí Wọ́n, ń pè ní [[hyperprolactinaemia]].
[[File:Zanzibar 31.JPG|thumb|240px|Breastfeeding of an older child]]