Osas Ighodaro
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Osas Ighodaro (bii ni ojo kerindinlogbon osu kewa) je osere ati atokun eto ni orile ede Naijiria ati Amerika. O gba ipo Omidan alawodudu ni Orile ede USA ni odun 2010. O da egbe Joyful Joy Foundation kale lati le doju ija ko aarun iba.[1][2] Ni odun 2014, o se atokun eto fun African Magic Viewers Choice Awards. O ko ipa Adanna ninu ere Tinsel. O si gba ebun osere to dara julo ni odun 2014 lati odo ELOY Awards[3][4].
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Osas Ighodaro | |
---|---|
Ighodaro co-hosting the Africa Magic Viewers Choice Awards in Lagos (2014) | |
Ọjọ́ìbí | Osariemen Martha Elizabeth Ighodaro October 26th New York City, United States |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian-American |
Iléẹ̀kọ́ gíga |
|
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–present |
Olólùfẹ́ | Gbenro Ajibade (m. 2015–2019) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Website | Official website |
Close