Richard Phillips (oníṣòwò ojú omi)
From Wikipedia, the free encyclopedia
Richard Phillips (bíi Ọjó kẹrindínlógún Oṣù karún Ọdún 1955[2]) jẹ́ oníṣòwò ojú omí ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí ó jẹ́ ògá ọkọ̀ MV Maersk Alabama nígbà tí àwọn ajalèlókun tí Somalia fẹ́ já ọkọ̀ náà gbà ní Oṣù kẹrin Ọdún 2009.
Quick Facts Ọ̀gá ọkọ̀, Ọjọ́ìbí ...
Ọ̀gá ọkọ̀ Richard Phillips | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kàrún 1955 (1955-05-16) (ọmọ ọdún 68) Winchester, Massachusetts, U.S. |
Orílẹ̀-èdè | ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà |
Iṣẹ́ | oníṣòwò ojú omi, akọ̀wé |
Gbajúmọ̀ fún | ọ̀gá ọkọ̀ ti MV Maersk Alabama nígbà Ìfipá Gba Maersk Alabama ní Ọdún 2009 |
Close