Tunde Idiagbon
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Babatunde Baku Abdul Idiagbon (14 September 1942 - 24 March 1999) jẹ́ ọmọ ológun ará ilẹ̀ Naijiria. Ní ọdún 1983 ó kópa nínú ifipágbàjoba lọ́wọ́ Ààrẹ Shehu Shagari, lẹ́yìn èyí ó di Ọ̀gá gbogbo ọmọọṣẹ́ ológun ní ibùjókó tó ga jù lọ ní ẹgbẹ́ àwọn ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, ipò yìí dúró gẹ́gẹ́ bí igbákejì Ààrẹ sí Muhammadu Buhari tó di Ààrẹ orílẹ̀-èdè. Idiagbon di ipò yìí mú láti 31 December, 1983 títí di 27 August, 1987 tí Ibrahim Babangida náà fi fipá gbàjọba.
Quick Facts Babatunde Idiagbon, 6th Chief of Staff, Supreme Headquarters ...
Babatunde Idiagbon | |
---|---|
6th Chief of Staff, Supreme Headquarters | |
In office 31 December 1983 – 27 August 1985 | |
Ààrẹ | Muhammadu Buhari as Military Head of State |
Asíwájú | Alex Ekwueme as civilian Vice President of Nigeria |
Arọ́pò | Ebitu Ukiwe |
Governor of Borno State | |
In office July 1978 – October 1979 | |
Asíwájú | Mustapha Amin |
Arọ́pò | Mohammed Goni |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | (1942-09-14)14 Oṣù Kẹ̀sán 1942 Ilorin, Kwara, Nigeria |
Aláìsí | 24 March 1999(1999-03-24) (ọmọ ọdún 56) Ilorin, Kwara, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | None (military) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Biodun Idiagbon |
Alma mater | Nigerian Military School Pakistan Military Academy Nigerian Defence Academy Naval Postgraduate School |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Adigun Nàìjíríà |
Years of service | 1962–1985 |
Rank | Major General |
Close
Bákan náà ló tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì nínú àwọn ìjọba ológun Naijiria láàrin ọdún 1966 sí 1979, tí ó jẹ́ olùdarí ológun ipinlẹ Borno lábẹ́ ìjọba ológun Olusegun Obasanjo.[1]